Ọ̀rọ̀ Kàbìtì: Èèyàn márùn-ún nínú ẹbí Òbílànà dèrò ọ̀run látàrí oúnjẹ tí wọ́n jẹ

A dé ilé àwọn mọ̀lẹ́bí Òbílànà láti bá wọn kẹ́dùn àti láti gbọ́ kúlẹ̀kúlẹ̀ ohun tó ṣẹlẹ̀ gan-an tó mú èèyàn márùn-ún nínú mẹ́fà dèrò ọ̀run alákeji lẹ́yìn oúnjẹ tí wọ́n jẹ. A bá ọ̀kan nínú àwọn mọ̀lẹ́bí náà sọ̀rọ̀, a bá ẹnìkan tó jẹ́ ará àdúgbò wọn sọ̀rọ̀ pẹ̀lú, wọ́n sì sọ irú ẹni

Read More