FÍDÍÒ: Ojú kálé: Àwọn ọmọ Nàìjíríà fi ẹ̀dùn ọkàn wọn hàn lórí àjálù tó ṣẹlẹ̀ ní Ọ̀wọ̀, ìpínlẹ̀ Oǹdó

A bá àwọn ọmọ Nàìjíríà sọ̀rọ̀ nípa àjálù tó ṣẹlẹ̀ ní Ọ̀wọ̀, ìpínlẹ̀ Oǹdó. Àwọn ènìyàn fi èrò wọn nípa ìṣẹ̀lẹ̀ náà hàn, wọ́n bá àwọn tí wọ́n pàdánù ẹ̀mí wọn kẹ́dùn, wọ́n sì mú ọ̀nà-àbáyọ wá lọ́lọ́kan-ò-jọ̀kan lórí bí a ṣe lè dáàbò bo ara wa.

Read More